Ní Ìbẹ̀ẹ̀rẹ̀ náà Gbogbo rẹ̀ ní àkókò kan, l’ọ́duń mélòó sẹ́yìn, Èmi ọmọkùnrin náà tí mo di àgbà: Lójijì ni ìgbésí ayé mi bẹ̀rẹ̀! Mo rí àgbayé níwájú mi— Nítorí náà Ọkùnrin òntúlẹ̀ náà ní ẹ̀gbẹ́ èèkàn àwọn ẹṣin rẹ̀, Ń làágùn ní ẹ̀bá òkè rẹ̀ àkọkọ́, Lẹ́hìn tí ó kúrò lẹ́ba àwọn erékùṣù Gbẹ́ kòtò ní àfonifojì nísàlẹ̀, Tí ó sì rí àwọn òkè ńlá láti máa ṣe ìtúlẹ̀, Akọ àpáta tí yóò pa ẹnu ohun ìgóko rẹ̀, Àrá ń rọ̀ lójú afẹ́fẹ́, Àti pé ténté dúdú tí ó wà l’ókè rẹ̀, ti dán, Ń dúró báyi. —Jẹ́kí ó túlẹ̀ bí ó bá láyà! | Entry #30209 — Discuss 0 — Variant: Not specifiednone
Voting points | 1st | 2nd | 3rd |
---|
20 | 4 x4 | 2 x2 | 0 |
- 1 user entered 2 "like" tags
Lójijì ni ìgbésí ayé mi bẹ̀rẹ̀! | Good term selection | splendidtransla No agrees/disagrees | |
Àti pé ténté dúdú tí ó wà l’ókè rẹ̀, ti dán, | Flows well | splendidtransla No agrees/disagrees | |
|
Ìbẹ̀rẹ̀ Lọ́gán ni gbogbo rẹ̰̀ ṣẹlẹ̀, ní àwọn ọdún kan sẹ́yìn, Ọmọdékùnrin tí mo jẹ́ di ọkùnrin: Lójijì ìgbé-ayé mi bẹ̀rẹ̀! Mo rí ayé níwájú mi— Nítorí náà Atúlẹ̀ yẹn nítòsí èèkàn àwọn ẹṣin rẹ̀ Nlàágùn lórí ténté òkè àkọ́kọ́, Lẹ́yìn tí ó ti kúrò níbi olómi náà Ó la aporo ní àfonífojì ìsàlẹ̀, Ó sì nrí ẹsẹ̀ òkè láti tú, Aṣálẹ̀ orí àpáta láti lo irin iṣẹ́ rẹ̀ ní àlòyọ́, Ààrá nrọ̀ dẹ̀dẹ̀ nínú afẹ́fẹ́, Ṣónṣó orí òkè dúdú náà sì wà lókè rẹ̀, ó ṣí sílẹ̀ Ó wá ndúró wàyí. —Jẹ́ kí ó tú ílẹ̀ náà tí ó bá tó bẹ́ẹ̀! | Entry #30038 — Discuss 0 — Variant: Not specifiednone
Voting points | 1st | 2nd | 3rd |
---|
13 | 2 x4 | 2 x2 | 1 x1 |
|
Ni Ibere Loju kan ni akoko yi, ni opolopo ọdun sẹyin, Ọmọkunrin ti mo je ti di ọkunrin bayi: Lojiji igbesi aye mi bẹrẹ! Mo ri ayé niwaju mi- Nitorina Atule na duro pelu awọn ẹṣin rẹ On laagun niwaju ori re, Lehin ti o ti fi awọn ipado silẹ Ati awon poro ni afonifoji ni isalẹ, Tí ó sì rí ibi òkè láti máa ṣe ìtúlẹ̀, Apata lasan to yo ba ohun itule re je, Ara nsan ninu afẹfẹ, Ti tente oke dudu ti o wa loke rẹ, si ndan, O nduro bayi. —Je ki o gbiyanju lat tule ti o ba lokan akin! | Entry #29513 — Discuss 0 — Variant: Not specifiednone
Voting points | 1st | 2nd | 3rd |
---|
5 | 0 | 1 x2 | 3 x1 |
|